Ààrẹ Buhari sọ̀kò ọ̀rọ̀ sáwọn tó kówó ìlú pamọ́

Ẹgbẹ́ Òsèlù APC, bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ lórí ìpàdé àpapọ̀ ẹgbẹ́
April 16, 2018
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Edo fòfin de dída ẹranjẹ̀ ńgbagba ìta
April 16, 2018
Ààrẹ Buhari sọ̀kò ọ̀rọ̀ sáwọn tó kówó ìlú pamọ́

Olórí orílẹ̀dè yi Àarẹ Muhammadu Buhari ti bẹnu àtẹ́luu bí àwọn tó sàkóso sẹ́yìn lórílẹ̀èdè yi se jí owó ìlú kóò.

Àarẹ Buhari sọ̀rọ̀ yi nílu London nígbà tí ẹgbẹ́ tó ń sàtìlẹyìn fún nílẹ̀ òkèèrè wa, kíì Àarẹ sàlàyé pé, ìjọba òun kò ní jáà àwọn aráalu ní tánmọ̀ọ̀, ó ní ó káa òun lára pé, ki-i-se gbogbo àwọn tó jí owó na kóò làwọn mọ̀, àti pé, ki-i-se gbogbo owó náà làwọn lè ríì gbà padà.

Àtẹ̀jáde látọ̀dọ̀ olùbádámọ̀ràn pàtàkì fún Àarẹ lórí ọ̀rọ̀ ìròyìn, ọ̀gbẹ́ni Fẹmi Adesina sọ pé, àsìsee àwọn adarí tẹ́lẹ̀rí lórílẹ̀èdè yi ló mú kí Nàijírìa wà nípò tó wà báyi.

Ogunkọla/Famakin

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *