Ajo IMF fi ireti han l’ori Idagbasoke Ile Naijiriya

Gomina Obaseki Gbegbese Otun Lori Eka Eto Eko
April 20, 2018
President Ramaphosa Leaves London over Protests in S/Africa
April 20, 2018
Ajo IMF fi ireti han l’ori Idagbasoke Ile Naijiriya

Ajo Ayanilowo L’agbaye, IMF, ti woye pe, nigba ti yoo ba fi di opin odun yii, eto oro aje orileede Naijiriya yoo ti goke si pelu ida meji ole die ninu ogorun.

Oludari eka to n risi Ise Iwadi labe ajo IMF, Ogbeni Maurice Obstfeld lo soro yi di mimo nibi apero awon oniroyin nilu Abuja.

O wa gbawon to n f’epo soro aje won, to fi mo Ile Naijiriya, lati fikun akitiyan won nidi gbigbeto oro aje ile yii gb’ona ibo min-in lo, pelu afikun pe, awon sin woo pe owo ori epo robi sii maa wale si l’ojo iwaju.

Ogbeni Obstfeld tun fikun alaye re pe, igbese jijawale owo ori epo robi naa si n tubo mu kowose awon orileede to nbe lapa ile Europe, Japan, China atile Amerika maa jafafa sii.

Kemi Ogunkola/Rotimi Famakin

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *