Ife ẹ̀yẹ bọọlu àgbáyé bẹ̀rẹ̀ ní Russia

Imam àgbà ilẹ̀’bàdàn: gba àwọn olósèlú nímọ̀ràn
June 14, 2018
Ìjọba Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti setán láti sàmúlò Ìmọ̀ ẹ̀rọ
June 14, 2018
Ife ẹ̀yẹ bọọlu àgbáyé bẹ̀rẹ̀ ní Russia

Pẹ̀lú bó se ku bí wákàtí diẹ tí ìdíje Ife ẹ̀yẹ àgbáyé tàjọ FIFA, fún tọdún yíì yóò bẹ̀rẹ̀, ojú gbogbo àgbáyé ti wà lára orílẹ̀-èdè tó ń gbàlejò ìdíje náà, ilẹ̀ Russia ti se ẹlẹ kọkànlélógún irú ẹ̀.

Wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ ètò ayẹyẹ fún ìsíde ìdíje náà, lẹ́yìn èyí nílẹ̀ Russia tó ń gbálejò ìdíje ọ̀hún, yóò wà máà na na tàn bí owó pẹ̀lú ikọ̀ ẹgbẹ́ Agbábọ̀lù Saudi Arabia ní pápá ìseré tó wà nílu Moscow.

Nígbà ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ̀lù ilẹ̀ wa Super Eagles yóò wako pẹ̀lú orílẹ̀dè Croatia lọ́jọ́ àbámẹ̀ta  ní dédé ago mẹ́jọ ajẹ́.

Kẹmi Ogunkọla

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *