Àarẹ ilẹ̀ Faranse gbàwọn ọ̀dọ́ nímọ̀ràn lórí isẹ́ ọ̀gbìn

Ilé isẹ́ elépo rọ̀bì mú àlékún bá epo rọ̀bì tó wà nípamọ́
July 4, 2018
Tour of Bodija Market, New Abattoir at Amosun Village
July 4, 2018
Àarẹ ilẹ̀ Faranse gbàwọn ọ̀dọ́ nímọ̀ràn lórí isẹ́ ọ̀gbìn

Àarẹ ilẹ̀ Faransé, Emmanuel Macron ti sèpàdé kan papọ̀ pẹ̀láwọn ọ̀dọ́ olókoowò bi ẹgbẹ̀rún méjì, nípínplẹ̀ Èkó.

Ètò náà èyí tí àjọ kan tó máà ńsètò ìrónilágbára fáwọn ọ̀dọ́ yíká ilẹ̀ adúláwọ̀, “Tony Elumelu Foundation” sàgbékalẹ̀ ni yóò fáwọn ọ̀dọ́ olókoowò náà lánfàní láti mú nínú omi ọgbọ̀n Àarẹ Macron, gẹ́gẹ́ bó se jẹ́ ọ̀kan gbógi nínú àwọn olórí orílẹ̀dè lẹ́nu lọ́lọ́ yíì.

Ìrètí àperò náà níràntí wà pé yóò mámugbòòrò bá àjọsepọ̀ tódọ́nmọ́rọ́n pẹ̀lú ilẹ̀ Faransé àtàwọn olórí olókowò nílẹ̀ Adúláwọ̀ tófimọ́àwọn tó ń sàgbékalẹ̀ òfin.

Sáájú lààrẹ Macron ti sọ́ọ́di mímọ̀ pé, ọ̀kan gbógì làwọn olùdókòòwò ilẹ̀ Adúláwọ̀ jẹ́ nídi mímú àyípadà rere bete ọrọ̀ ajé lágbayé.

Lána òde yíì láarẹ ilẹ̀ Faransé sàbẹ̀wò sáarẹ Muhammọdu Buhari nílu Abuja.

Kẹmi Ogunkọla/Adeitan

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *