Ìpínlẹ̀ Òndó sàgbékalẹ̀ àkànse ìgbìmọ̀ Ìgbẹ́jọ́

Govt Urged to Tackle Scarcity of Pharmaceutical Materials
July 4, 2018
Ilé isẹ́ elépo rọ̀bì mú àlékún bá epo rọ̀bì tó wà nípamọ́
July 4, 2018
Ìpínlẹ̀ Òndó sàgbékalẹ̀ àkànse ìgbìmọ̀ Ìgbẹ́jọ́

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Òndó ti gbèrò láti sàgbákalẹ̀ àkànse àbá òfin ilé-ẹjọ́ kan, èyí tí yóò tètè yanjú gbogbo àwọn gbungbun àtàwọn nípínlẹ̀ náà.

Nígbà tó ń báwọn oníròyìn sọ̀rọ̀, lẹ́yìn ìpàdé ọlọ́jọ́ méjì ìgbìmọ̀ alásẹ Ìpínlẹ̀ náà, tó wáyé nílu Àkúrẹ́, alákoso fétò ìdájọ́ nípínlẹ̀ Òndó, ọ̀gbẹ́ni kọ́lá Olawoye sọ pé, èróngbà àgbékalẹ̀ àbá òfin náà ni láti tètè máà yanjú àawọ̀ ọ̀rọ̀ ilẹ̀, tigbeyawo, tétò ìsúná .

ọ̀gbẹ́ni Ọlawọye tún sàlàyé pé, àbá òfin náà yóò fàyè sílẹ̀ láti sàtúngbèyẹ̀wò gbogbo áawọ̀ tó ti wáyé sẹ́yìn, tí yóò sì fòpinsí láisi ìdádúró kankan tó bá ti di òfin tán.

Kẹmi Ogunkọla/Abiọla

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *