ọ̀gá Ọlọ́pa laagogo ìkìlọ̀ fáwọn olósèlú

Breaking: Thai Cave Rescue Mission in Success
July 10, 2018
INEC Tasks Electorate on Cordial Relationship with Ad-hoc Staff
July 10, 2018
ọ̀gá Ọlọ́pa laagogo ìkìlọ̀ fáwọn olósèlú

ọ̀gá Ọlọ́pa patapata nílẹwa, Ibrahim Idris ti sèkìlọ̀ pé, olósèlú tọ́wọ́ bátẹ̀ pé òun kó àwọn jàdùkù káakiri lásìkò ìdìbò ni yóò fojú winá òfin.

ọ̀gbẹ́ni Idris ẹnitó sèkìlọ̀ yi nílu Adó-Èkìtì rọ àwọn olùgbé Ìpínlẹ̀ Èkìtì láti máà da àsẹ ọlọ̀pa nù kíwọ́n sì sọwọ́pọ̀ láti jẹ́kí ètòdìbò náà lọ nírọwọ rọsẹ̀.

Ó sàlàyé pé, gbogbo ẹgbẹ́ òsèlú àti àjọ INEC, láwọn yóò sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú láti jẹ́kí isẹ́ wọn kẹ́sẹjárí .

ọ̀gbẹ́ni Idris wá rọ àwọn èèyàn Ìpínlẹ̀ Èkìtì láti máà fi gbogbo bí ǹkan se ńlọ tó ilésẹ́ ọlọ́pa létí lásìkò ìdìbò náà.

Kẹmi Ogunkọla/Lọlade Afonja

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *