Onímọ̀ Ìlera gba ìyálọ́mọ nímọ̀ràn lórí ìlera ọmọwẹrẹ

Don Advocates Financial Support to Boost Food Production
July 11, 2018
Fayose Attack: Police takes over Government House
July 11, 2018
Onímọ̀ Ìlera gba ìyálọ́mọ nímọ̀ràn lórí ìlera ọmọwẹrẹ

Ẹnìkan ti sọpé, àwọn ìyálọ́mọ nílò láti yàgò kúrò nídi míma sí àwọn ọmọ wọn sótutù, lọ́nà àti dènà àwọn àisàn tólè tìdí irúfẹ́ ìgbésẹ̀ náà súyọ.

Onítọ̀hún ní òsìsẹ́ elétò ìlera kan nílé ẹ̀kọ́sẹ́ ìsègùn ńlá UCH, Ìbàdàn Arábìnrin Grace Ajayi, tó sì sàlàyé pé, àwọn ọmọdé paapa jùlọ àwọn ìkókó máà wọ àwọn asọ òtútù fún, kíwọ́n sì máà bòwọ́n mọ́ra daada.

Arábìnrin Ajayi tọ́kasi pé, míma bo àwọn ọmọ ìkókó àtọmọ́dé mọ́ra dada lákokò yíì àti fífún wọn lọ́yàn lásán fódidi osù mẹ́fà láifi ǹkankan láà se pàtàkì púpọ̀, láti dábòbò wọn kúrò lọ́wọ́ òtútù àyà.

Ó wá gbàwọn ìyálọ́mọ nímọ̀ràn láti máà mọ́rọ̀ ìgbáyégbádùn àwọn ọmọ lọ́kunkúndùn lóre koore.

Kẹmi Ogunkọla/Kẹhinde

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *