Àarẹ ilé ìgbìmọ̀ Asòfin àgbà gbóríyìn fún Adele Àarẹ

Implication of Gale of Defections
August 8, 2018
Senato Adeleke: Ilé ẹjọ́ gíga wọ́gilé ẹ̀sùn ìwé-ẹ̀rí
August 8, 2018
Àarẹ ilé ìgbìmọ̀ Asòfin àgbà gbóríyìn fún Adele Àarẹ

Àarẹ ilé ìgbìmọ̀ Asòfin àgbà Bikọla Saraki ti ńbawọn aráálu sọ̀rọ̀ níbi àpérò àwọn oníròyìn kan lágbayé .

Àarẹ ilé ìgbìmọ̀ Asòfin náà ló léwájú àwọn ọ̀gá àgbà lọ síbi ètò náà.

Ó wá bu ẹnu àtẹ́ lu rògbòdìyàn tó wáyé nílé ìgbìmọ̀ asòfin lána, èyí tí ẹ̀ka ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ dá sílẹ̀.

Èyí tó sọ pé óbu epo sásọọ álàa Ìjọba àwarawa.

Tó sì gbóríyìn fún Adele àrẹ Yẹmi Ọsinbajo fún ìgbésẹ̀ kọ́mọ́nkìa tó gbé.

Net/Wojuade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *