Sẹnatọ Abiọla Ajimọbi gbàwọn olùdíje nímọ̀ràn

Ilé-isẹ́ ọlọ́pa kó àwọn ọlọ́pa lọ sí Ìpínlẹ̀ Ọsun
September 12, 2018
Court Remands PDP Chieftain, Chief Bisi Ilaka in Agodi Prison
September 12, 2018
Sẹnatọ Abiọla Ajimọbi gbàwọn olùdíje nímọ̀ràn

Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, Sẹnatọ Abiọla Ajimọbi ti gbàwọn olùdíje sípò Gómìnà lábẹ́ àsìa ẹgbẹ́ òsèlú APC, láti dìjọ se ìdúnadúrà láàrin arawọn, kíwọ́n yan èèyàn mẹ́ta péré tí yóò díje níbi ètò ìdìbò abẹ́nú látilè ra tíkẹ̀tì ipò Gómìnà.

Níbi ìpàdé kan tó se pẹ̀lẹ́wọn asájú ẹgbẹ́ òsèlú náà àtàwọn olùjíje lábẹ́ àsìa ẹgbẹ́ ọ̀hún tó wà ládugbò Òkè-Àdó nílu Ìbàdàn ni Gómìnà ti sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀, pẹ̀lú àlàyé pé, ó se pàtàkì kíwọ́n gbé ìgbésẹ̀ náà fánfàní ẹgbẹ́ òsèlú àtàwọn olùdíje ọ̀hún láti yàgò fún ìgbésẹ̀ kólùdíje tólé mẹ́rìnlélógún máà lọ fétò ìdìbò abẹ́nú ẹgbẹ́ òsèlù kan.

Net/Fọlakẹmi Wojuade

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *