Àwọn Alásẹ Àjọ NPA Jẹjẹ Láti M’amáyédẹrùn Lẹ́ka ọ̀ún

Adarí Ilé Asòfin Àgbà Gba Àwọn Olùdìbò Nímọ̀ràn
September 19, 2018
Osun in Historical Perspective
September 20, 2018
Àwọn Alásẹ Àjọ NPA Jẹjẹ Láti M’amáyédẹrùn Lẹ́ka ọ̀ún
NPA Boss, Hadiza Bala Usman

Àwọn alásẹ tó ńrísí ibùdó ọkọ̀ ojú-omin ilẹ̀ Nàijírìa NPA, sọpé àgbéyẹ̀wò lórí àjọ tí yóò máà sàmójútó ibùdó náà ti déè ìpele tó nítumọ̀ tí yóò sìjẹ́ bíbuwọ́lù lósùkejìlá ọdún yíì.
Olùdarí àgbà ilésẹ́ NPA, Hadiza Bala Usman, sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀ nílu Abuja níbi ìpàdé àpérò ẹgbẹ́ àwọn tó ńrísí ibùdó ọkọ̀ ojú-omin nílẹ̀ Africa.
Ó sàlàyé pé, ìgbésẹ̀ náà yóò mu àgbéga tónítumọ̀ báà ìgbòkè-gbodò ọkọ̀ ojú-omin nílẹ̀ yíì, pẹ̀lú àtọ́kasí pé, ilésẹ́ NPA, ńsisẹ pọ̀ pẹ̀lú Bánki àgbáyé, àtàwọn àjọ min láti ridájú ìfẹ̀nukò ọ̀rọ̀ jẹ́ èyítómúná dóko.
Olùdarí àgbà Bọla Usman wá fikun ọ̀rọ̀ rẹ́ẹ̀ pé, ìgbésẹ̀ náà yóò fáà ojú àwọn olùdókòwò aládani mọ́ra sílẹ̀ Nàijírìa tó sì fọwa sọ̀yà pé ìjọba kòní káàrẹ láti máà pèsè àwọn oun amáyédẹrùn tóòye fẹ́ka ọ̀ún.
Wale Asakẹ/Kẹmi Ogunkọla

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *