Emà yansẹ́lódì, NNPC rọ NUPENG àti PENGASSAN

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ sún àsìkò ìwọlé padà
September 24, 2018
FRCN máwọn oludíje APC fún ipò Gòmìnà wásíwáju aráálu
September 24, 2018
Emà yansẹ́lódì, NNPC rọ NUPENG àti PENGASSAN

Ọga àgbà àjọ elépo rọ̀bì lórílẹ́èdè yíì, ọ̀mọ̀wé Maikanti Baru ti rọ àwọn òsìsẹ́ lẹ́ka ìpèsè epo rọ̀bì láti fọwọ́wọ́nú, kíwọ́n sì sọ́ọ̀ ìyansẹ́lódì tíwọ́n fẹ́ gùnlé rọ̀ọ̀ náà.

Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òsìsẹ́ tí wọ́n ń pèní NUPENG àti PENGASSAN, ni wọ́n láwọn fẹ́ dasẹ́ sílẹ̀ .

Nínú àtẹ̀jáde tí, ọ̀mọ̀wé Baru fisíta, ó pàrọwà sí ẹgbẹ́ òsìsẹ́ na, pé kí wọ́n máse se ohukóhun tólè fáà èdè àyedè lẹ́ka iléésẹ́ ìpèsè epo rọ̀ọ̀bì.

Kẹmi Ogunkọla

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *