Àkànse ètò tí iléésẹ́ Radio Nàijirìa gbé kalẹ̀ láti fi jẹ́ kí aráálu mọ́ọ̀ àwọn tí wọ́n gbérò àti jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ yóò wáyé lọ́la àti ọ̀túnla.
Ètó oníwàkàtí méjí náà yo ma gorí afẹ́fẹ́ ní ìkànnì ta wa yíì Premier F.M 93.5 àti Amúludun F.M 99.1 ní déedé áàgo mẹ́wa òwúrọ̀.
Àwọn tó ń ní èróngbà àti díje fún ipò Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ láti ẹgbẹ́ òsèlú APC, ni yo wa sórí ètò náà.
Àwọn aréélé na le dá sí ètò ọ̀ún nípa fifíì àtẹ̀jísẹ́ ránsẹ́ sí nọ́mbà ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ yíì 08180000935 tàbí 09060008935.
Kẹmi Ogunkọla