Ilé ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ sún àsìkò ìwọlé padà

Fight Against Human Trafficking: NAPTIP Rescues Over 4000 Victims
September 24, 2018
Emà yansẹ́lódì, NNPC rọ NUPENG àti PENGASSAN
September 24, 2018
Ilé ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ sún àsìkò ìwọlé padà

Àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ orílẹ̀èdè yíì tisún àsìkò tí wọ́n o wọlé padà sẹ́nu isẹ́ di ọjọ́ kẹsan osù tó ńbọ̀.

Akọ̀wé ilé ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ náà, ọ̀gbẹ́ni Sani Omolori, tó kéde ọ̀rọ̀ yíì nílu Abuja, sàlàyé pé ètò ìdìbò abẹ́nú tó ńwáyé nínú ẹgbẹ́ òsèlú méjèejì, tó tóbi jù nílé asòfin àpapọ̀ ló jẹ́ kí wọ́n sún ọjọ́ àti ìwọlé síwájú.

Ọgbẹni Omolori wá ní wọ́n ń retí kí gbogbo àwọn asòfin na padà sẹ́nusẹ́ ní déédé àgo mẹ́wa òwúrọ̀ lọ̀jọ̀ kẹsan osù tó ń bọ̀.

Kẹmi Ogunkọla

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *