Ajọ eleto ilera agbaye pe fun afojusun ilera ọpọlọ awọn ọmọde ati ọdọ

NIPOST Commences Bank Services
October 10, 2018
Ileṣẹ ifiwe ranṣẹ sina eto ifowopamọ
October 10, 2018
Ajọ eleto ilera agbaye pe fun afojusun ilera ọpọlọ awọn ọmọde ati ọdọ

Ajọ eleto ilera agbaye, WHO, ti ke si awọn orilede nilẹ Adulawọ, paapaa awọn to nkoju rogbodiyan awọn agbesunmọmi, lati ṣafoju sun seto ilera ọpọlọ awọn ọmọde atawọn ọdọ.

Ninu atẹjade kan lati sami ayẹyẹ ayajọ ọjọ ilera ọpọlọ lagbaye, ajọ WHO bere fun ṣiṣayẹwo ipo tọpọlọ wa, lorekore paapaa fawọn eewe.

O wa rọ awọn adari nilẹ adulawọ lati ṣagbekalẹ ohun iro-lagbara ọkan o jọkan eto fawọn ọdọ pẹlu iranlọwọ ileṣẹ to n ṣe sagbekalẹ ilana ati eto gbogbo pẹlu ṣiṣeto ilera ọpọlọ lawọn ilewosan alabọbe gẹgẹ bi ajọ ọhun ṣe wi pe, mẹwa ninu ogun awọn ọmọde atawọn ọdọ ni ipinija ọpọlọ kan tabi omi n ba fira.

”Awọn ọdọ ati eto ilera pẹlu ayipada to nde ba aye” ni akori ayajọ ọjọ ilera ọpọlọ lagbaye  fun tọdun yii.

Kemi Ogunkola

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *