Ileṣẹ ifiwe ranṣẹ sina eto ifowopamọ

Ajọ eleto ilera agbaye pe fun afojusun ilera ọpọlọ awọn ọmọde ati ọdọ
October 10, 2018
Police Parades Suspected Robbery Gangs
October 10, 2018
Ileṣẹ ifiwe ranṣẹ sina eto ifowopamọ

Ileṣẹ ifiwe ranṣẹ orilede yii NIPOST, ti npese opo ayelujara ilana min-in.

Olufiwe-ranṣẹ agba nilẹ yii, ọgbeni Bisi Adegbuyii losipaya ọrọ yii nilu Ọyọ nibi ayẹyẹ ayajọ ifiwe ranṣẹ lagbaye tọdun yii.

Ọgbeni Adegbuyii sope ilana titun ọhun nii ṣeto ifowopamọ pẹlu ileṣẹ ifiwe ranṣẹ, salaye siwaju pe igbesẹ ọtun naa waye kileṣẹ ọhun leewa nibamu pẹlu bi ilana fifi nkan sọwọsira ẹni ṣewa lagbaye bayii.

O wa kede pe, awọn eeyan lee ṣi aṣunwọn ifowopamọ, gbowo tabi fowo ranṣẹ leyikeyi ileṣẹ ifiwe ranṣẹ nilẹ Nigeria pẹlu ilana titun ohun.

Kemi Ogunkola

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *