E je Asojurere – Awon Oba Alaye Si Oloselu

Defend the Interest of the People – Ooni, Alaafin to Politicians
October 12, 2018
Atiku seeks Obasanjo’s Support
October 12, 2018
E je Asojurere – Awon Oba Alaye Si Oloselu

Awọn Eekan Oba alaye nile Yoruba, Ooni ile Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi ati Alaafin Oyo, Oba Lamidi Adeyemi ti ke si awon oloselu ile yoruba lati maa se oju awon eniyan won daradara ki won o si ya go fun iwa imo tara eni nikan ati lilo ipo won fun iko ro jo.

Awon Oba Alaye naa mu imoran yii wa nibi apero kan to da lori bi nkan se ri lorileede bayi, ti igbimo Isokan Yoruba gbekale nilu Ikenne, nile parakoyi oloselu nni, oloogbe Obafemi Awolowo.

Akoroyin wa Wale Oluokun wa nibe, abo re re.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *