Ijọba Ọṣun ti Kede Eto Ilana F’ọdun Mẹwa

United Nations at 73 Years
October 24, 2018
Six Winners Emerge in Yoruba Essay, Reading Competition
October 24, 2018
Ijọba Ọṣun ti Kede Eto Ilana F’ọdun Mẹwa

Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti kede eto ilana ọlọdun mẹwa eyi to niiṣe pẹlu ọrọ aje ati igbayegbadun agbegbe.

Alakoso feto iṣuna ati idagbasoke nipilẹ Ọṣun, Ọmọwe Ọlalekan Yinusa to yọju ọrọ yi sita nilu Ileṣa nibi ipade kan sọ pe igbesẹ yi yoo fopin si aṣa pipa iṣẹ akanṣe ti.

O ṣe lalaye pe ilana ọlọdun mẹwa yi awọn tọrọ kan nidi  eto ọrọ aje to fi mọ awọn oniroyin ni yoo lọwọ ninu ikẹsẹjari eto naa.

Ọmọwe Yinusa fikun alaye pe eto ohun yoo mu ki ipinlẹ Ọṣun wuyi loju awọn ajọ agbaye ati awọn to le fẹ ṣeranwọ fun ti yoo si mu adinku ba iṣẹ aṣepa

Adenitan /Ogunkọla

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *