Super Falcons Kogoja lati Kopa Ninu Aṣekagba Idije Ife Ẹyẹ Agbaye

Ẹgbẹ Afẹnifẹre nfẹ ki wọn Gbaṣẹ lọwọ awọn Oga Oṣiṣẹ Alabo
November 28, 2018
Be Dogged in The Pursuit of Excellence, Women Charged
November 28, 2018
Super Falcons Kogoja lati Kopa Ninu Aṣekagba Idije Ife Ẹyẹ Agbaye

Ẹgbẹ agbọọlu Super Falcons tilẹ wa ti kogoja lati kopa ninu aṣẹkagba  ife ẹyẹ agbayeto nwaye nilẹ Ghana.

Awọn ọmọbinrin tilẹ wa fagba han ẹgbẹ agbabọọlu Lioness ti Cameroon pẹlu ayo mẹrin si meji.

Pẹlu igbesẹ yi, ilẹ wa Naijiria ni akọkọ orilẹede Adulawọ ti yoo wẹ yan kainkain lati le kopa ninu idije ife ẹyẹ Agbaye fun ti awọn agbabọọlu obinrin ti yoo waye lọdun 2019.

Kẹmi Ogunkọla

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *