Ìjọba Àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ akin lórí ríra ohun ìjà ogun

Ìjọba Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ sọ kọ́kọ́rọ́ sẹ́nu ọ̀nà ilé ẹ́kọ́ girama kan
December 4, 2018
Ogun Approves Grant for Community Development Associations
December 4, 2018
Ìjọba Àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ akin lórí ríra ohun ìjà ogun

Ilé isẹ́ àarẹ ti pàsẹ pé kí àwọn ohun èèlò ìjagun máà jẹ́ rírà látọ̀dọ̀ àwọn tó ńrọ wọ́n ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà ìjọba àpapọ̀.

Alákoso ètò àbò Mansur Muhammed tó pàsẹ bẹ́ẹ̀ tún gbé olùdarí àwọn ọmọ ogun orí ilẹ̀, ọ̀gágun Tukur Bratai nídi láti lọ fi agbègbè ìlà oorùn àriwà ilẹ̀ Nàijírìa se ibùjóko títí tí ìlú ó fi fara rọ níbẹ̀.

Alákoso sàlàyé pé, Àarẹ Buhari tún pàsẹ pé kí ilé isẹ́ ológun sèètò ìmáyédẹrùn fáwọn jagunjagun tó wà lójú ìjà níbi gbogbo tí mìmì ti ńmì ní Nàijírìa.

Kẹmi Ogunkọla/Ayankọsọ

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *