Àarẹ Buhari se Filọ́lẹ̀ Abala Kejì Ìlànà Ètò Ìlera Arálu

Àwọn Mọ́gàjí Fọwọ́ Ìbágbépọ̀ Àláfìa Sọ̀yà
January 9, 2019
Ọkọ̀ Àjàgbé Nlá Sekúpa Obìnrin Kan Nílu’bàdàn
January 9, 2019
Àarẹ Buhari se Filọ́lẹ̀ Abala Kejì Ìlànà Ètò Ìlera Arálu

Àarẹ Muhammadu Buhari ti se filọ́lẹ̀ abala kejì ìlànà ètò ìlera fún sáà ọdún 2018 sọ́dún 2022, láti ridájúpé ètò ìlera tópọ̀jù-owó kari tólórí tẹlẹ̀mù nílẹ̀ yíì.

Nígbà tó ńsọ̀rọ̀ níbi ètò náà nílu Abuja, Àarẹ Buhari tọ́kasi pé, ìgbésẹ̀ náà jẹ́ ara ìlànà láti sàseyọrí nídi ríridájúpé ètò ìlera tooyekon kárí gbogbogbò nílẹ̀ Nàijírìa.

Bákana lótún sísọ lójú ìgbésẹ̀ sísèto abala kini owó ìpèsè ètò ìlera tójẹ́ Billiọnu márùndínlọ́gọ́ta naira fún Ìpínlẹ̀ mẹ́fà tófimọ́ olú-ìlú ilẹ̀ yíì.

Àarẹ Buhari wá fikún ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé, ìlànà àtẹ́lé ti wanlẹ tí yóò mú kí sísètò owóna ọ̀hún jẹ́ àkóyawọ́ àti gbangbalàsáta.

Mnt/Idogbe/Afọnja/Ogunkọla

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *