Àwọn Mọ́gàjí Fọwọ́ Ìbágbépọ̀ Àláfìa Sọ̀yà

Osun: Corps Member Charged for Reckless Driving
January 9, 2019
Àarẹ Buhari se Filọ́lẹ̀ Abala Kejì Ìlànà Ètò Ìlera Arálu
January 9, 2019
Àwọn Mọ́gàjí Fọwọ́ Ìbágbépọ̀ Àláfìa Sọ̀yà

Olúbàdàn ilẹ̀ Ìbàdàn, Ọba Saliu Adetunji tikésí àwọn mọ́gàjí tọ́rọ̀ rógbòdìyàn tó wáyé lọ́jọ́ ìsinmi tó kọjá kan, láti sèkìlọ̀ fáwọn èèyàn tówà lẹ́kùn kówá wọn láti yàgò kúrò nídi ìwà jàgídí-jàgan.

Ọba Adetunji sàlàyé ìdí tó fi se pàtàkì kópin déébáa ìwà jàgìdí-jàgan nípínlẹ̀ Ọyọ.

Diẹ lára àwọn mọ́gàjí náà wá fọwọ́-sọ̀yà pé ìpàdé ti wáyé yóò so èso rere láti fẹsẹ̀ òfin àti àláfìa múlẹ̀ láwọn agbègbè mọ́rọkàn.

Àwọn mọ́gàjí ọ̀hún wá sèlérí láti láà àwọn èèyàn kóówá wọn lọ́ọ̀yẹ̀ lórí òfin tórọ̀mọ́ dída omi àláfìa àwùjọ rú.

Mnt/Afọnja /Ogunkọla

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *