Ọkọ̀ Àjàgbé Nlá Sekúpa Obìnrin Kan Nílu’bàdàn

Àarẹ Buhari se Filọ́lẹ̀ Abala Kejì Ìlànà Ètò Ìlera Arálu
January 9, 2019
Trailer Crushes Woman to Death in Ibadan
January 9, 2019
Ọkọ̀ Àjàgbé Nlá Sekúpa Obìnrin Kan Nílu’bàdàn

Arábìnrin kan ló salábàpàdé ikú òjiji lorọ òní níbi ìsẹ̀lẹ̀ ìbàmbá ọkọ̀ àjàgbé ejò lásìkò tófẹ́fo títì márosẹ̀ mọ̀lété.

Gẹ́gẹ́ bí ẹnití ọ̀rọ̀ náà sojúrẹ sewí pé, arábìnrin náà fẹ́ fóò títì márosẹ̀ mọ̀lété sódìkejì ni kótó dipé ẹsẹ̀ rẹ̀ yọ́ọ̀ tí ọkọ̀ elépo ńlá ọ̀hún si gorírẹ, pẹ̀lú àlàyé pé àwọn mẹ́ta lófẹ́ fo títì ọ̀hún táwọn méjì tó kùsìti kọjá lọ kí ìsẹ̀lẹ̀ náà tó se sokan lárawọn.

Àmọ́sá, àwọn àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó tigbé òkú arábìnrin náà lósí ilé ìgbókusí.

Makinde/Idogbe/Afọnja/Ogunkọla

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *