Ìjọba Àpapọ̀ yo sọ Àsọyán lórí Owó Osù Tuntun

Houthis’ Drone Attack Kills Six Soldiers in Yemen
January 10, 2019
Ìpínlẹ̀ Èkìtì Fọwọ́sí Àsùnwọ̀n kan soso tí Wọ́n ó ma Sanwó Sí fún Ìjọba
January 10, 2019
Ìjọba Àpapọ̀ yo sọ Àsọyán lórí Owó Osù Tuntun

Àarẹ Muhammadu Buhari sọ wípé ìfikùnlukùn yo wáyé lórí àwọn òsìsẹ́ tó wà lákàsọ̀ owó osù tó kéréjù, sùgbọ́n tíwọ́ngba owó osù tó kọja ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n naira.

Àarẹ sọ̀rọ̀ yí níbi ìfilọ́lẹ̀, ìgbìmọ̀ tí yo ma rísí ọ̀rọ̀ owó osù tó kéréjù, fáwọn òsìsẹ́ nílẹ̀ Nàijírìa.

Àarẹ Buhari tọ́kasi pé, ó se pàtàkì láti jẹ́ káwọn tọ́rọkàn mọ̀ nípa ìgbésẹ̀ náà, kó má ba báwọn lẹ̀jafuu.

Ìjọba ní ìdunna-dúrà pẹ̀lú àwọn asojú òsìsẹ́ yo ma tẹ̀síwájú lẹ́yìn t’àbá fún owó osù tuntun ọ̀hún báti di òfin tán.

Ìgbésẹ̀ náà wáyé lẹ́yìn ti ko ti ju wákàtí mẹ́rin lé lógún tí fẹnukò wáyé pé àbá fún owó osù òsìsẹ́ tó kéréjù tuntun gbọ́dọ̀ jẹ́ fi sọwọ́ sílé ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ kótó di ọjọ́ kẹtàlélógún osù yí.

Afọnja/Net

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *