Onidajo Agba laago ikilo fawon adajo

Idibo: Amoran lo sodo omo ile Naijiria latodo MMPN
February 16, 2019
Imbibing the Spirit of Good Sportsmanship as Election
February 16, 2019
Onidajo Agba laago ikilo fawon adajo

Adele Adajo Agba ile yii, Onidajo Tanko Muhammed ti laago ikilo seti awon adajo ti yoo seto ejo to ba suyo, latara idibo lati rip e won segbe tabi faramo egbe oselu Kankan.

Onidajo Mohammed to yoju oro yii sita lasiko to nbura fawon adajo metadinlogun ti yoo dari awon igbimo oludajo esun to ba suyo nibi idibo odun 2019, ro won lati bowo fun ofin ile yii ki won o si se ose ti won gbele won lowo lai segbe.

O ni ki won mase jeki idunkoko moni tabi ihale domi tutu si won lokan lati sise won pelu ibowo fun ofin ati idajo aisegbe.

Ogunkola/Olarinde

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *