Editor

February 9, 2018

Àjọ INEC bèrè fún àtìlẹyìn lórí ojútu sí ìsòro ètò ìbò

Àjọ elétò ìdìbò nílẹ̀yí, INEC, ti bèèrè fátìlẹyìn àjọ tón gbógunti sísowó ìlú kúmọkùmọ EFCC, nídi àti wójùtú sọ̀rọ̀ ìbì […]
February 9, 2018

ìlànà míma gbẹ́jọ́ kawájú ilé-ẹjọ́ nílànà ẹ̀rọ ayélujára Kònípẹ́ wáyè

Kònípẹ́ tíwọ́n yóò fi sèfilọ́lẹ̀ ìlànà míma gbẹ́jọ́ kawájú ilé-ẹjọ́ nílànà ẹ̀rọ ayélujára èyí tí yóò jẹ́ fáwọn èèyàn àwùjọ […]
February 9, 2018

Osun College of Health Technology Reopens Next Week

The Osun State House Assembly has assured students of School of Health Technology, Ilesa that the institution will reopen for […]
February 8, 2018

The Media as Tool for Promoting Peace

All over the world, the powers of media and its professionals are so enormous that they can bring down any […]
February 8, 2018

Police Parades Suspected Ritualists in Ibadan

Nigeria Police Oyo State Command has paraded some suspected ritualists with human head and hands. The suspects were paraded alongside […]
February 8, 2018

Gómìnà Akinwunmi Anbọde seléri àtìlẹyìn fún ilésẹ́ ológun

Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó, Akinwunmi Anbọde ti fọwọ́ ìdánilójú sọ̀yà pé, ìsèjọba tó ún ńléwájú yóò tẹ̀sìwájú láti ma sàtìlẹyìn fún […]
February 8, 2018

Ètò ẹ̀kọ́ kíkọ́ tipadà bọ̀ sípò nílé ẹ̀kọ́ Olùkọ́ni àgbà Emmanuel Alayande

Ètò ẹ̀kọ́ kíkọ́ tipadà bọ̀ sípò nílé ẹ̀kọ́ Olùkọ́ni àgbà Emmanuel Alayande ọ̀yọ́, lẹ́yìn ìyansẹ́lódì kan tẹ́gbẹ́ òsìsẹ́ mẹ́tẹ̀ta tówà […]
February 8, 2018

Àwọn èèkàn nílẹ̀ Ìjẹ̀shà sàbẹ̀wò ìkẹ́dùn sí ilésẹ́ Gold F.M,

Àwọn èèkàn nílẹ̀ Ìjẹ̀shà, àwọn ìjọ ẹ̀sìn àtàwọn afẹ́nifẹ́re tí túbọ̀ sàbẹ̀wò ìkẹ́dùn sí ilésẹ́ Radio Nigeria Gold F.M, iléshà […]
February 8, 2018

Awọn olùgbọ́ rọ òsìsẹ́ ìròrìn làti ma sisẹ́ pẹ̀lú ìkóraẹni-níjanu

Ó se pàtàkì káwọn òsìsẹ́ ìròrìn ma sisẹ́ pẹ̀lú ìkóraẹni-níjanu, ìfọkànsì, ìfiranijìn sisẹ́ lai bẹ̀rù tàbí sègbè fẹ́nìkan. Èyí jẹ́ […]
Prev page

Next page