Yoruba

April 10, 2019

Ètò àpérò ọlọ́jọ́ mẹ́ta tí ílesẹ́ Radio Nigeria ìbàdàn kásẹ̀ nílẹ̀

Ètò àpérò ọlọ́jọ́ mẹ́ta lórí àwọn ǹnkan tí yóò máà jáde lórí afẹ́fẹ́ nílesẹ́ Radio Nigeria ìbàdàn ti kásẹ̀ nílẹ̀ […]
April 9, 2019

Ọwọ́ pálába ọmọkùnrin kan ségi ńigba tó ńgbo owó lẹ́nu ẹ̀rọ lái lo káàdi

Ọjọ́ gbogbo ni tolè ọjọ́ kan ni tolóhun, báyíì ni ọ̀rọ̀ rí ní òwúrọ̀ òní ní ẹnu ẹ̀rọ tó ńpọ […]
April 9, 2019

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn, jẹ́jẹ ìpèsè ètò ìlera tó péjú owó

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn sàtẹnúmọ́, títẹramọ́ àfojúsùn rẹ̀ sétò ìlera tó péjuówó fáwọn èèyàn rẹ̀. Alákoso fétò ìlera nípinlẹ̀ Ògùn, Dókítà […]
April 3, 2019

Ilé Asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ pèfún ìlanilọyẹ̀ lórí ìlòkulò òogùn

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ ti késí àwọn ẹ̀ka alásẹ láti gùnlé ìlanilọ́yẹ̀ ìtagbangba lórí ìdí tó fiyẹ láti dẹ́kun […]
April 3, 2019

Ìjọba Àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ akin lórí àyíká

Ìjọba àpapọ̀ ti sọ pé òun kógìrì mọ́ àyíká tó wuyì fún àwọn ilésẹ́ níbamu pẹ̀lú ohun tó fún ọ̀rọ̀ […]
March 27, 2019

Fífi Ìwé ẹ̀rí ọjọ́ ìbí ọmọ sílẹ̀ pẹ̀lú ìjọba se pàtàkì – Gómíná Akeredolu

Ìwé ẹ̀rí fífi ọjọ́ ìbí ọmọ sílẹ̀ pẹ̀lú ìjọba ló ti pa dandan fún gbogbo ọmọ tó bá fẹ́ lọ […]
March 27, 2019

Ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀yí tise ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá

Ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀yí tise ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá tóhun fún àwọn akọ́sẹmọ́sẹ́ láti ilé isẹ́ ètò ìsúná, ìsirò owó, ilé isẹ́ […]
March 22, 2019

INEC Kede Atundi Ibo Lawon Ipinle Kan

Ajo Eleto Idibo, INEC ti kede pe ohun yo seto idibo Gomina ati tile Asofin lawon ipinle mejidinlogun ti idibo […]
March 20, 2019

Ilé ẹjọ́ sún ìgbẹ́jọ́ Gómìnà síwájú ńipinlẹ̀ Ọsun

Ilé ẹjọ́ tó ńgbọ́ awuyewuye tó súyọ lásìkò ìdìbò sípò Gómìnà nípinlẹ̀ Ọsun èyí tó jóko nílu Abuja, ni yo […]