Yoruba

December 5, 2018

Ìjọba Àpapọ̀ fi gbèdéke lélẹ̀ lórí píparí isẹ́ ọkọ̀ ojú irin ilẹ̀ èkósí Ìbàdàn

Ìjọba àpapọ̀ ti fi gbèdéke titun lélẹ̀ lórí àsepárí isẹ́ àkànse ojú ọ̀nà ọkọ̀ ojú-irin Èkó sí Ìbàdàn tolódiwọ̀n ìgbàlódé, […]
December 5, 2018

Igbákejì Àarẹ kọminú lórí báwọn èèyàn se ńpọ̀si lórólẹ̀-èdè yi

Igbákejì Àarẹ, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo sọ pé, báwọn èèyàn se ńpọ̀si lórílẹ̀-èdè yíì lè sokùnfà ìpèníjà fúnlẹ̀ Nàijírìa nígbà ta […]
December 4, 2018

Ìjọba Àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ akin lórí ríra ohun ìjà ogun

Ilé isẹ́ àarẹ ti pàsẹ pé kí àwọn ohun èèlò ìjagun máà jẹ́ rírà látọ̀dọ̀ àwọn tó ńrọ wọ́n ní […]
December 4, 2018

Ìjọba Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ sọ kọ́kọ́rọ́ sẹ́nu ọ̀nà ilé ẹ́kọ́ girama kan

Ìjọba Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ titi ilé ẹ̀kọ́ girama ti ìjọba tó wà lágbègbè Olódó ní ìlú Ìbàdàn pa lẹ́yẹ ò sọkà. […]
November 28, 2018

Super Falcons Kogoja lati Kopa Ninu Aṣekagba Idije Ife Ẹyẹ Agbaye

Ẹgbẹ agbọọlu Super Falcons tilẹ wa ti kogoja lati kopa ninu aṣẹkagba  ife ẹyẹ agbayeto nwaye nilẹ Ghana. Awọn ọmọbinrin […]
November 28, 2018

Ẹgbẹ Afẹnifẹre nfẹ ki wọn Gbaṣẹ lọwọ awọn Oga Oṣiṣẹ Alabo

Ẹgbẹ Afẹnifẹre  ti ke si Aarẹ Muhammadu Buhari lati jawe ile fun gbogbo awọn ọga oṣiṣẹ eleto aabo latari iṣẹlẹ […]
November 23, 2018

Radio Nigeria gun Oṣiṣẹ Kẹsẹ lori Igbejade Eto Idibo

Amọran ti lọ sọdọ oṣiṣẹ ileeṣẹ Radio Nigeria lati maa ṣiṣẹ wọn bo titọ ati botiyẹ, paapa julọ nidi gbigbe […]
November 23, 2018

Ajọ EFCC Gbẹsẹle Dukia Fayoṣe

Awọn oṣiṣẹ ajọ EFCC yabo ilu Ado-Ekiti, ti wọn si gbẹsẹle awọn ile kan to ṣeeṣe ko jẹ ti Gọmina […]
November 15, 2018

Onimọ ke Gbajare lori Aito Oṣiṣẹ Lẹka Ilera

Ọga Agba ajọ to n ri si ipeniye ounjẹ ati oogun nilẹwa, (NAFDAC) ọjọgbọn Mojisọla Adeyẹyẹ ti ke si ta […]