ípínlẹ̀ ọ̀sun

September 23, 2018

Awon oludibo soro lori aseyori eto idibo ipinle Osun

Awon oludibo ti di alaafia to joba ninu eto ibo si ipo gomina ni ipinle Osun mo eto abo to […]
September 17, 2018

Ìjọba àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ láti mú àgbéga bá ẹ̀ka Ìlera

Gẹ́gẹ́bí ara akitiyan ìjọba àpapọ̀ láti mú kí ìpèsè ètò ìlera aláabọ́dé túbọ̀ gbé pẹ́ẹ́lí si, àarẹ Muhamadu Buhari yo […]
September 13, 2018

A kì se agbẹnusọ Ìjọba nìkan – iléésẹ́ Radio Nigeria

Iléésẹ́ Radio Ìjọba àpapọ̀, Radio Nigeria ti mu dáà àwọn èèyàn orílẹ̀dè yi lójú pé, òun kò ní káàrẹ láti […]
September 12, 2018

Ilé-isẹ́ ọlọ́pa kó àwọn ọlọ́pa lọ sí Ìpínlẹ̀ Ọsun

Sáajú ètò ìdìbò sípò Gómìnà ti yóò wáyé nípínlẹ̀ Ọsun, ilé-isẹ́ ọlọ́pa ilẹ̀ yíì ti kó àwọn òsìsẹ́ ọlọ́pa tó […]
September 12, 2018

Ètò àríyànjiyàn fáwọn olùdíje sípò Gómìnà nípínlẹ̀ ọ̀sun ńlọ lọ́wọ́

Ètò àríyànjiyàn fáwọn olùdíje sípò Gómìnà níbi ètò ìdìbò sípò Gómìnà tó ńbọ̀ lọ́nà nípínlẹ̀ ọ̀sun, èyí tílesẹ́ wa Radio […]
September 6, 2018

Radio Nigeria Ìbàdàn sagbátẹrù Ètò iforowanilenuwo nípínlẹ̀ Ọsun

Ètò  iforowanilenuwo  láarin àwọn olùdíje sípò Gómìna tí yóò wáyé nípínlẹ̀ Ọsun èyí tílesẹ́ Radio Nigeria Ìbàdàn sagbátẹrù rẹ̀, yóò […]
August 8, 2018

Senato Adeleke: Ilé ẹjọ́ gíga wọ́gilé ẹ̀sùn ìwé-ẹ̀rí

Ilé ẹjọ́ gíga Ìpínlẹ̀ Ọsun wọ́gilé ẹ̀sùn ìwé-ẹ̀rí ayédèrú táwọn kan fikan olúdíje fún ipò Gómìnà, lábẹ́ òsèlù PDP, fún […]
August 31, 2017

Ìpínlẹ̀ ọ̀sun pèsè ọkọ̀ ọ̀fẹ́ fáwọn arìnrìnàjò

Kò dín láwọn arìnrìn àjò bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta tó tí jànfàní látara abala àkọ́kọ́ ètò ìrìnà ọkọ̀ ojúrin ọ̀fẹ́, èyí […]
August 29, 2017

Arẹ́gbẹ́sọlá pèfún ìsọkan fún ìtẹ̀síwájú orílẹ̀èdè yíì

Ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀sun nfẹ́ káwọn èèyàn ilẹ̀ yíì gbe gbogbo ìwà to balè tako ìgbáyégbádùn tàbí ìdásílẹ̀ tóníse pẹ̀lú ẹ̀sìn […]