Àmọ̀ràn lọ́ sọ́dọ̀ Mùsùlùmí láti máà kó àkóyawọ́

NANS Protests State of Education in Ogun
October 3, 2017
Ìjọba àpapọ̀ sèlérí ìfẹsẹ̀múlẹ̀ ọrọ̀ ajé
October 3, 2017
Àmọ̀ràn lọ́ sọ́dọ̀ Mùsùlùmí láti máà kó àkóyawọ́

Wọ́n tí gba àwọn mùsùlùmí tówà ní ìjọba nímọ́ràn láti ipò wọ́n nínú ayédèrú fáwọn èèyàn.

Èyí ní àfẹnuko àwọn olùdánilẹ́kọ níbi ètò kan tó wáyé níbàdàn.

Olùkọ́ kan ní fásitì ìbàdàn, ọ̀jọ̀gbọ́n Abdurahaman Olóyedé nínú ìdánilẹ́kọ́ rẹ̀ rọ àwọn mùsùlùmí láti kó àkóyawọ́ nínú ohun gbogbo tí wọ́n ba ń se.

Nínú ìdánilẹ́kọ míràn , Ṣheikh Dhukralah Shaffi gba àwọn adarí  ẹ̀sìn níyànjú láti máà gbàdúrà fáwọn alásẹ, paapaa jùlọ àwọn tó dí ipò òsèlú mú.

Alága níbi ètò náà onímọ̀ ẹ̀rọ Rauf Ọlánìyan sọ pé, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Nàijírìa kó tíì dé ibi tó yẹ́ lẹ́hìn ọdún kẹtàdínlọ́gọ́ta òmìnira síbẹ̀ ìdàgbà sókè tó ní tunmọ̀ tí de báà.

Ogunkọla.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *