Ìpínlẹ̀ Òndó gbé ìgbésẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ ìdaranjẹ̀

Herdsmen Threat: Fayose Raises Bar on Security
January 10, 2018
Àjọ elétò ìdìbò fí àtẹ ìlànà ìdìbò síta.
January 11, 2018
Ìpínlẹ̀ Òndó gbé ìgbésẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ ìdaranjẹ̀

Ẹnìkan tí se onìgbọ̀wọ́ àbá òfin kan ibi táwọn darandaran yóò tí máà daranwọn jẹ̀, síwájú ilé ìgbimọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Òndó.

Nígbà tó ńgbé kawájú ilé onígbọ̀wọ́ àbá ofin náà, ọ̀gbẹ́ni Gbénga Ọbaweya, sàlàyé pé, àbá ofin náà sapàtàkì níwòye sí awuyewuye tó n wáyé pẹ̀láwọn adaranjẹ̀ lórílẹ̀dè yíì, ọ̀gbẹ́ni Ọbaweya wá ké sáwọn asòfin náà láti gbé ìgbésẹ̀ kíakía lórí àbá òfin náà,fánfàní àwọn àgbẹ̀ tó n bẹ nípínlẹ̀ náà.

Nínú ọ̀rọ̀ táwọn àgbẹ̀ méjì kan, Ajaguntẹyin tí Stephen Daramọla, àtarábìnrin Beatrice Kọlawọle, mẹ́nuba ìrírí wọ́n pẹ̀láwọn darandaran àti ìbẹ̀rùbojo ìkọlù wọ́n tó se e se kówáyé lọ́jọ́ iwájú.

Nígbà tó ń fèsì, alaga ìgbìmọ̀ tẹ̀kótó ilé fétò ọ̀gbìn, ọ̀gbẹ́ni Towase Kuti rọ àwọn èèyàn láti se suuru, gẹ́gẹ́ bo se jẹ́ pé, àwọn asòfin ọ̀hún yóò gbé àwọn ìgbésẹ̀ tó béyẹ lórí àbá òfin náà láti le sọ́ọ́di òfin níkúnkún.

Ogunkọla

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *