Àjọ INEC Sèlérí ètò ìdìbò ti kò lẹ́ja ńbákàn nínú

PDP Loses Bid to Stop Ondo Council Poll
March 9, 2018
Candidates in Ibadan Describe UTME as Hitch Free
March 9, 2018
Àjọ INEC Sèlérí ètò ìdìbò ti kò lẹ́ja ńbákàn nínú

Àjọ elétò ìdìbò nílẹ̀ wa, INEC, ti ní àlàkalẹ̀ lóníruru èyí tí yóò mú ètò ìdìbò ti kò lẹ́ja ńbákàn nínú lọ́dún 2019.

Lára àwọn ìgbésẹ̀ yí ní ti ìforúkọsílẹ̀ fún àwọn tó ti tó ìbò dí àti gbígba káádi ìdìbò tó fo mọ́ ìlànà ààtẹ̀lé bẹ̀rẹ̀ láti ọdún 2017 ti di ọdún 2021.

Ogá àjọ elétò ìdìbò fún ìpìnlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Mutiu Adegoke, ló yọjú ọ̀rọ̀ yí síta nígbà tó ńbá àwọn akọròyìn sọ̀rọ̀ ńí ìpínlẹ̀ ọ̀yọ̀.

Ó sọ síwájú pé, ètò ìlanilọ́yẹ̀ náà tún ńtẹ̀síwájú lórí gbígbé káádi ìdìbò àti fíforúkọsílẹ̀ lákọ̀tun fáwọn ti kò báà ti sebẹ.

Ọgbẹni Adegoke wá rọ àwọn onísẹ́ ìròyìn láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àjọ INEC, ko báà lè se àseyọ́rí lórí àwọn ètò rẹ̀ lọ́kan òjọ̀kan.

Ogunkọla/Adu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *