Àmọ́ràn lọ sọ́dọ̀ àwọn obìnrin láti fọwọ́sọwọ́pọ̀ fún ìdàgbàsókè

ODHA, Ajimobi Lauds FG on Dapchi School Girls Release
March 22, 2018
Ọba Alayé fọnrere lílọ́wọ́ àwọn ọ̀dọ́ nínú ètò ọ̀gbìn
March 22, 2018
Àmọ́ràn lọ sọ́dọ̀ àwọn obìnrin láti fọwọ́sọwọ́pọ̀ fún ìdàgbàsókè

Àwọn obìnrin niwọ́n ti gbà nìmọ̀ràn láti ní ìpinnu, kíwọ́n léè débi àfojúsùn wọn.

Alága ẹgbẹ́ àwọn oníròyìn nílẹ̀ Nàijírìa ẹ̀ka ti ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Adewumi Faniran ló sọ̀rọ̀ ìyànjú yíì, níbi àpérò àwọn obìnrin oníròyìn tó wáyé pẹ̀lú àkòrí XALOUD 2018

The Panelists addressing gender issues

The Panelists addressing gender issues

Ọgbẹni Faniran sàlàyé pé, àwọn obìnrin nílò láti dìde láiwo ti ìpèníjà tówà níwájú wọn, kíwọ́n léè débi gíga láwùjọ.

Ẹnitó dári ọ̀rọ̀ níbi àpérò ọ̀hún nílu bàdàn, Arábìnrin Adefẹmi Bucknor-Aderibigbe sọpé, àwọn obìnrin nílò láti máà sátìlẹyìn fúnra wọn.

Ó rọ àwọn akọ́sẹ́ mọsẹ́ oníròyìn láti máà fọ́wọsowọ́pọ̀ lórí àwọn ohun tó lè mú àyípadà rere bá àwùjọ.

Ogunkọla/Deen

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *