Ìjọba àpapọ̀ kẹ́ẹ́fín ayédèrú òsìsẹ́ ọlọ́pa

Radio Nigeria Ibadan Facilitates Sade’s Rehabilitation
March 26, 2018
Ilé asòfin gbésẹ̀ láti mú àtúnse bá òfin tó rọ̀mọ́ gbèsè
March 26, 2018
Ìjọba àpapọ̀ kẹ́ẹ́fín ayédèrú òsìsẹ́ ọlọ́pa

Ìjọba àpapọ̀orílẹ̀èdè yi sọ pé, àwọn ayédèrú òsìsẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n tí wọ́n ń gbowó níleesẹ́ ọlọ́pa, ni àsírí wọn ti túù, táwọn si ti yọ orúkọ wọn kúrò nínú àwọn tí ìjọba ń sanwó fúnwọn.

Ìwádi fihàn pé, ǹkan bíì ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọ̀tàlélọ́ọ́dúrún àti mẹ́wa ọlọ́pa ló wà nínú àkọsílẹ̀ orúkọ àwọn ọlọ́pa tó ńsisẹ́ lọ́dọ̀ ìjọba àpapọ̀.

Pẹ̀lú bí àkan se wá rí yíì, òpin yo débáá bí wan se ń yọ́ọ̀ ọmọ àwọn ọlọ́pa níyọkúyọ nítorí pé, láti sìnsiyi lọ́ọ̀, tààràtà ní owó osù àwọn ọlọ́pa yo máà tẹ wọn lọ́wọ́ láti ọ́fìsì asirò owó àgbà.

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti wá sọ pé, òun ti pinnu láti rí dájú pé, gbogbo òsìsẹ́ ìjọba àpapọ̀ pátá ní wọ́n ń gbà owó osù wọn tààràtá látọ̀dọ̀ asírò owó àgbà lórílẹ̀èdè yíì.

Ogunkọla/Net

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *