Akitiyan bẹ̀rẹ̀ lórí àti dẹ́kun dída isẹ́ onísẹ́ kọ

Civil Servants Appeal for Review of NHF, Minimum Wage
April 9, 2018
Ilẹ̀ Nàijírìa se ojúse sí àjọ Ìsọ̀kan àgbáyé
April 9, 2018
Akitiyan bẹ̀rẹ̀ lórí àti dẹ́kun dída isẹ́ onísẹ́ kọ

Wọ́n ti ńsètò bí wọ́n ó se se ohun èlò ẹ̀rọ Kọmputa kan, èyí tí wọ́n léè ma lò láti fi dẹ́kun ìwà dídaa isẹ́ onísẹ́ kọ́ọ̀.

Akọ̀wé àjọ tó ń bójútó àwọn iléékọ fasiti lórílẹ̀èdè yi, NUC, ọ̀jọ̀gbọ́n Abubakar Rasheed ló kéde ọ̀rọ̀ yi níbi ètò ìdánilẹ́kọ kan tí wọ́n se nílu Abuja èyí tó dá lóríi àtúntò ètò ẹ̀kọ́ gíga nílẹ̀ Africa.

Ó tọ́ka si pé, àwọn ǹkan tí kò tọ́ọ̀ tó ma ń wáyé láwọn iléékọ gíga bíì, kí wọ́n ma tètè gbé èsì ìdánwò jáde, bíbèèrè owó kí èèyàn tó lè mú mááki tó dára, àti díden kókó mọ́ní nípa ọ̀rọ̀ ìbálòpọ̀ àti, ọ̀jsgbọ́n Rasheed sàlàyé pé, àwọn ìwà báyi ń sàkóbáa fún ìpèníjà àwọn akẹ́kọjáde lórílẹ̀èdè yi.

Akọ̀we àjọ NUC, na sọ pé èyí ló jẹ́ kí àjọ na gbé ìgbìmọ̀ kan dìdee èyí tí ọ̀gbẹ́ni Peter Okebukọla jẹ́ adarí fún láti wá ojútu si ọ̀rọ̀ náà.

Ogunkọla/Net

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *