Ìjọba Àpapọ̀ gbé Ìgbésẹ̀ lórí àmúgbòòrò ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn

Protecting and Preserving the Environment
June 8, 2018
Ìjọba Àpapọ̀ ńfẹ́ kópin débá ìwà ìjínigbé lẹ́kùn Niger Delta
June 8, 2018
Ìjọba Àpapọ̀ gbé Ìgbésẹ̀ lórí àmúgbòòrò ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn

Ààrẹ orílẹ̀dè yíì Muhammọdu Buhari ti késí ilé-ìfowópamọ́ ilẹ̀ adúláwọ̀ tó ń sàkóso kíkó ọjà wọlé àti fífi sọwọ́ sílẹ̀ òkèrè, láti jẹ́kí ìlànà owówa rẹ̀, se dédé àgbékalẹ̀ ètò ìjọba tó wà lóde báyíì lórí àmúgbòòrò ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn.

Nígbà tó ńgba Àarẹ ilé-ìfowópamọ́ náà, tí tún se alága ìgbìmọ̀ àwọn olùdarí ilé ìjọba, Àarẹ Buhari sọ́ọ́di mímọ̀ pé, ilẹ̀ Nàijírìa sì ni ẹni tó yẹ kó jànfàní owóya ilé-ìfowópamọ́ náà jùlọ.

Ó wá wòye pé, pẹ̀lú bó se ńyánwọn ilé-isẹ́ ajé àtẹlẹ́kajẹ̀ka lówó nílẹ̀ Nìajírìa, ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn nìkan ni kò ti jẹ̀ gbádùn owóya náà tó bẹ̀ jubẹlọ, tí sì nílò kìwọ́n sisẹ́ lórí tiẹ náà.

Níbi ìpàdé náà lààrẹ Buhari tún ti pàsẹ, fákọ̀wé àgbà síjọ̀ba àpapọ̀ ilẹ̀ yíì, ọ̀gbẹ́ni Boss Mustapha, láti bálàkoso fólùlùú’lẹ̀ wa Abuja sèpàdé lórí fífọwọ́sí ilẹ̀ tíwọn yóò fikọ́ ẹkùn olúle ìfowópamọ́ náà, àtàwọn min-in fágbekalẹ̀ àwọn ibùdó ẹ̀ka ìlera tíwọ́n ńgbèrò lóluulú ilẹ̀ wa Abuja.

Kẹmi Ogunkọla/Net

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *