Ìpínlẹ̀ Ògùn sèlérí líla ojútó omi láti dènà ẹ̀kún omi

Amosun Decorates Government House Police Officers
July 16, 2018
Suspected Killer Boyfriend Remanded in Prison
July 16, 2018
Ìpínlẹ̀ Ògùn sèlérí líla ojútó omi láti dènà ẹ̀kún omi

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn ti sèlérí láti gùnlé ìgbésẹ̀ líla ojúnà tí omi yóò máà gbà sàn gẹẹrẹgẹ láti dènà ìsẹ̀lẹ̀ ẹ̀kún omi.

Gómìnà Ibikunle Amosun ló sọ̀rọ̀ yi nígbà tó lọ sàbẹ̀wò sí àwọn ibití ẹ̀kún omi ti sọsẹ́ tó sì pa tó èèyàn méje.

Gómìnà tún sàlàyé pé ọ̀pọ̀ àwọn ilégbetó ńdi ọ̀nà omi ni yóò di wíwó, ó sì wá gba àwọn olùgbé Ìpínlẹ̀ náà nímọ̀ràn láti máà gba ìwé àsẹ ìkọ́lé kí wọ́n tó máà kọ́lé.

Kẹmi Ogunkọla/Fọlarin

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *