Ètò àríyànjiyàn fáwọn olùdíje sípò Gómìnà nípínlẹ̀ ọ̀sun ńlọ lọ́wọ́

FRCN Pledges Continuous Promotion of Good Governance
September 12, 2018
Ilé-isẹ́ ọlọ́pa kó àwọn ọlọ́pa lọ sí Ìpínlẹ̀ Ọsun
September 12, 2018
Ètò àríyànjiyàn fáwọn olùdíje sípò Gómìnà nípínlẹ̀ ọ̀sun ńlọ lọ́wọ́

Ètò àríyànjiyàn fáwọn olùdíje sípò Gómìnà níbi ètò ìdìbò sípò Gómìnà tó ńbọ̀ lọ́nà nípínlẹ̀ ọ̀sun, èyí tílesẹ́ wa Radio Nigeria Ìbàdàn sàgbékalẹ̀ rẹ̀, tí ńlọ lọ́wọ́ nílé ìtura Brymo Okinni, tó wà lógú ọ̀nà Ilobu, nílu Osogbo nípínlẹ̀ Ọsun.

Àtẹ̀jáde kan tálàgbà ìgbìmọ̀ fétò ìdìbò níle sẹ́ náà, alàgbà Adenrele Ajisefinni fisíta, sọ́ọ̀di mímọ̀ pe, ètò àríyànjiyàn náà yóò fáwọn olùdíje náà lánfàní láti sọ gbogbo ohun tíwọ́n bá ní fáràlú, àtàwọn ohun tétò ìpolongo ìbò wọn dá lé lórí.

Net/Fọlakẹmi Wojuade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *