Ìpínlẹ̀ Ọsun, Kẹbbi gùnlé dídókowò nípasẹ̀ ǹkan àlùmọ́nì

Onímọ̀ ètò ìsúná fẹ́ káwọn ọnílésẹ́ ajé daradé ètò ìróni làgbàra ijoba
January 31, 2019
Osun Government Voids Installation of Alara of Ara
January 31, 2019
Ìpínlẹ̀ Ọsun, Kẹbbi gùnlé dídókowò nípasẹ̀ ǹkan àlùmọ́nì

Ìpínlẹ̀ Kẹbbi àti Ọsun ni yo dókowò nídi ẹ̀ka àlùmọ́nì inú ilẹ̀.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kẹbbi Àlhájì Atiku Bagudu àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọsun, ọ̀gbẹ́ni Isyaka Oyetọla ló sọ̀rọ̀ yi nílé àrẹ lábuja.

Gómìnà Bagudu sọ pé, àwọn fẹ́ gbé ìgbésẹ̀ yi níbamu pẹ̀lú bí ìjọba àpapọ̀ se fẹ́ kétò ọrọ̀ ajé pínsí yẹ́lẹ yẹ̀lẹ, nípa dídókowò lẹ́ka ètò ọ̀gbìn àti ohun àlùmọ́nì inú ilé, óní Àarẹ Buhari ti pá lásẹ pé, kí ìpínlẹ̀ Kẹbbi sisẹ́ láti mú àyípadà bá ẹ̀ka tí wọ́n ti wa àlùmọ́nì, kọ́rọ̀ ajé lè rú gọ́gọ́ si.

Bakana, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọsun, ọ̀gbẹ́ni Isyaka Oyetọla sàlàyé pé, Ìpínlẹ̀ Ọsun ní àwọn àlùmọ́nì inú ilẹ̀ bi góòlu, pẹ̀lú àfikún òun yo se àmúlò àlùmọ́nì yi dada àti wípé oun yo sisẹ́ tọ́ọ̀ mímú àgbéga bá ẹ̀ka ọ̀hún.

Net/Afọnja

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *