Ajọ Eleto Idibo Kede Afikun Ọjọ Igba Kaadi Idibo

Ekiti Govt. Distribute Furniture, Modern Science Textbooks
February 8, 2019
Ijọba Apapọ fi Araalu Lọkan Balẹ Lori Aabo Lọjọ Idibo
February 8, 2019
Ajọ Eleto Idibo Kede Afikun Ọjọ Igba Kaadi Idibo

Ajọ eleto Idibo, INEC, ti ṣe afikun ọjọ gbigba kaadi idibo alaope.

Alaga ajọ INEC, Ọjọgbọn Mahmood Yakubu lo joju ọrọ yii sita nibi ipade to ṣe pẹlu awọn alakoso idibo.

Ọjọ kọkanla oṣu yii ni gbigba kaadi alalope naa yoo wa sopin.

Fadahunsi/Ogunkola

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *