Ijọba Apapọ fi Araalu Lọkan Balẹ Lori Aabo Lọjọ Idibo

I will run an inclusive government – Alao Akala
February 9, 2019
Ajọ Eleto Idibo Kede Afikun Ọjọ Igba Kaadi Idibo
February 10, 2019
Ijọba Apapọ fi Araalu Lọkan Balẹ Lori Aabo Lọjọ Idibo

Olubadamọran Agba lori ọrọ aabo nilẹ yii, Mohammed Monguno ti fi awọn ọmọ ilẹ yii lọkan balẹ pe ko ni tẹti nidi iṣẹ wọn lasiko idibo to nbo.

Ọgbẹni Monguno fọwọ ọrọ yii sọya nibi apero kan, eeyi tajọ eleto idibo gbe kalẹ ni Abuja.

O yan pe, Aarẹ Muhammad Buhari nigbẹkẹle ninu eto idibo to muyanyan.

Ọgbẹni Munguno tun fi daju pe awọn ọmọ ilẹ yii yoo lanfani lati dibo labẹ aabo to peye laisi idun koko mọni, o wa gba awọn oṣiṣẹ alaabo nimọran lati maṣe ṣe ohun to le sakoba fun ikẹsẹjari idibo.

Ogunkọla/Ṣọpẹ

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *