Ipolongo ibo Aare Buhari: Eto abo buyari si ni ipinle Ogun

President Buhari’s Campaign: Security Beefed up in Ogun
February 10, 2019
Oyo NUP Appeals to HOS over Gratuities
February 11, 2019
Ipolongo ibo Aare Buhari: Eto abo buyari si ni ipinle Ogun

Eto abo ti buyari si bayii loluulu ipinle Ogun nigbaradi feto ipolongo ibo egbe oselu All Progressive Congress, APC.

Gege bagbenuso ile-ise olopa ile yii, eka tipinle Ogun, Ogbeni Abimbola Oyeyemi, se wipe gbogbo awon osise eka ile-ise na lo ti wa lawon ibi to se koko nipinle naa nimurasile fabewo Aare.

Ile’se Radio Nigeria jabo pe, gbogbo ilu Abeokuta tisolulu ipinle Ogun lo ti mo tonitoni ni igbaradi fun eto ipolongo ibo oun.

Bakanna, lajo ton ri soro awon patako ipolongo oja nipinle Ogun ti si gbogbo awon iwe ikede tiwon ti le mawon ara ogiri to wa loju ona papa isere MKO Abiola nigba tagbase se kan to wa nidi awon ise akanse kan nilu Abeokuta ti fikun akitiyan won.

Nigbaradi fabewo Aare ni itesiwaju eto ibo re, saaju ni won tikoko sun eto naa nipinle Ogun losu tokoja nitori alowo ise akanse oko ojurin eko sibadan tiwon sefilole re, eyi tiwon lo wa lara igbaradi abewo re ohun.

Oluokun/ Wojuade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *