Gbèdéke gbígba káádi ìdìbò wá sópin

Iléésẹ́ ọlọ́pa sèlérí, àabò tó péye lásìkò ìbò
February 11, 2019
Ìpínlẹ̀ Ọyọ ní ọ̀gá ọlọ́pa tuntun
February 11, 2019
Gbèdéke gbígba káádi ìdìbò wá sópin

Òní ni ètò gbígba káadi ìdìbò PVC, yo wa sópin.

Alága àjọ elétò ìdìbò lórílẹ̀èdè yi, INEC, ọ̀jọ̀gbọ́n Mahmood Yakub sọ pé, lẹ́yìn òní, àwọn káadi ìdìbò tá wọn tó ni wọ́n kò bá wá gbáà, làwọn o lọ ko pamọ́ sí bánki àpapọ̀ orílẹ̀èdè yi, títí di ẹ̀yìn ètò ìdìbò, nígbà tí wọ́n ó tóò láafani àti gba wọ́n táwọn ti ko i ti forúkọ sílẹ̀ tẹ́lẹ̀ na yo si lanfani àti se bẹ.

A ó rántí pé, alága àjọ, INEC, ló fíì ọjọ́ mẹ́ta kún àsìkò tí àwọn aráalu yo fi lánfani àti gbáà káadi ìdìbò náà èyí tó yẹ kó ti wá sópin, lọ́jọ́ ẹtì tó kọjá.

Adu/Ogunkọla

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *