Àjọ tó ńbójútó iléésẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ laago ìkìlọ̀ lórí ìdìbò tó ńbọ̀

Àmọ̀ràn lọ sọ́dọ̀ àwọn ọ̀dọ́ láti yàgò fún jàgìdìjàgan
February 13, 2019
Oyo Pensioners Threaten Protest over Unpaid Allowances
February 14, 2019
Àjọ tó ńbójútó iléésẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ laago ìkìlọ̀ lórí ìdìbò tó ńbọ̀

Wọ́n ti kílọ̀ fáwọn iléesẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti àwọn olósèlú nípínlẹ̀ Ọyọ láti máse si iléésẹ́ ìròyìn lò gẹ́gẹ́bí àjọ tó ń bójútó ilesẹ́ ìgbóhùn sáfẹ́fẹ́ ko se ní bèsù bẹ̀gà láti fìyà jẹ ẹnikọ̀kàn tó bá ya elétí ikún tàbí ilésẹ́ ìròyìn tó bá tẹ òfin àjọ náà lójú.

Olùdarí àjọ tó ń bójútó ilésẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́, ẹ̀ka tìlú Ìbàdàn arábìnrin Ọlajumọkẹ Ọginni ló sọ bẹ́ẹ̀ nígbà tó ń sọ̀rọ̀ lórí àyájọ́ ọjọ́ ìgbóhùn sáfẹ́fẹ́.

Arábìnrin Ọginni sàlàyé pé, ilésẹ́ ìròyìn gbọ́dọ̀ gbájúmọ́ àwọn ọ̀rọ̀ tó se kókó kíì se láti máà dojú ìjàkọra ẹni.

Arábìnrin Ọginni sọ pé ọ̀kan ójókan ètò ìlanilọ́yẹ̀ niwọ́n ti gùnlé lórí báwọn ilésẹ́ ìròyìn se lè máà hùwà akasẹ́mọsẹ́ nípa lílo èdè ọmọlúabi.

Ogunkọla/Kẹhinde

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *