Ẹgbẹ́ àwọn Musulumi oníròyìn nípinlẹ̀ Ọyọ dùnú pẹ̀lú Seyi Makinde

Tribunal Grants APC’s Candidate Leave to Check Electoral Materials
March 13, 2019
Ẹgbẹ àwọn ọmọbíbí Ìlú Ìbàdàn sèlérí àtìlẹyìn fún Gọ́mìnà tílu díbò yàn
March 13, 2019
Ẹgbẹ́ àwọn Musulumi oníròyìn nípinlẹ̀ Ọyọ dùnú pẹ̀lú Seyi Makinde

Ẹgbẹ́ àwọn Musulumi oníròyìn nípinlẹ̀ Ọyọ ti dáwọ́ ìdùnú pẹ̀lú Seyi Makinde tẹgbẹ́ òsèlú PDP.

Nínú isẹ́ ìkíni kú oriire alága ẹgbẹ́ , MMPN, ẹ̀ka tìpínlẹ̀ Ọyọ Àlhájì Ridwan Fasasi, sọ pé, àbájade èsì ìdìbò náà fi ìfẹ́ táwọn aráalu ní hàn fún ọ̀gbẹ́ni Seyi Makinde.

Wọ́n wòye pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìrírí Gómìnà tíwọ́n díbò yàn nídi isẹ okòwò àti wa ìfifúni tóò sèrànlọ́wọ́ gidigidi láti lè se fẹ àwọn araalu.

Ègbẹ́ Musulumi oníròyìn wá rọ Gómìnà tílu dìbò yàn láti sètò ìjọba pẹ̀lú ọkan tó tẹ lai sègbè fẹ́nikẹ́ni nípa ẹ̀sìn, ẹ̀yà tàbí ibi yowu tóníkálùkù ti wá.

Wọ́n rọ ọ̀gbẹ́niMakinde láti nawọ́ ìfẹ́ sí gbogbo àwọn alátakò kósì pe aseyọri rẹ̀ jẹ́ ti gbogbo ìlú.

Iyaniwura/Fasasi

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *