Ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀yí tise ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá

I will improve on my achievements – Governor Okowa
March 27, 2019
Fífi Ìwé ẹ̀rí ọjọ́ ìbí ọmọ sílẹ̀ pẹ̀lú ìjọba se pàtàkì – Gómíná Akeredolu
March 27, 2019
Ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀yí tise ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá

Ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀yí tise ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá tóhun fún àwọn akọ́sẹmọ́sẹ́ láti ilé isẹ́ ètò ìsúná, ìsirò owó, ilé isẹ́ epo rọ̀bì, tófimọ́ èyí tón rísí àatò gbogbo lọ́nà àti ríì dájúpé àkọsílẹ̀ tó yanrantí lórí ẹ̀rọ ayélujára láti ilé isẹ́ epo rọ̀bì ilẹ̀yí rẹ́sẹ̀walẹ̀.

Lákoko tónsọ̀rọ̀ níbi ìpàdé ìgbìmọ̀ ìfilọ́lẹ̀ ọ̀hún nílu Abuja, olùdámọ́ràn pàtàkì lórí àatò gbogbo sí lakóso ìpínlẹ̀ fún epo rọ̀bì, ọ̀gbẹ́ni Tom Okon sọpé, wọ́n se àgbékalẹ̀ ìgbìmọ̀ ọ̀hún láti ridájú pé àkọsílẹ̀ lórí ẹ̀rọ ayélujára lẹ́ka epo rọ̀ọ̀bì se dédé.

Ófikun ọ̀rọ rẹ̀ pe, pàtàkì ìgbìmọ̀ ọ̀hún ní láti jẹ́kí ọwọ́ isẹ́ óyá, tófimọ́ ètò ìpowówọlé lábẹ́lé kórẹ́sẹ̀walẹ̀.

Olùdámọ́ràn pàtàkì ọ̀hún fikun ọ̀rọ rẹ̀ pe ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá na táwọn alákoso fún owónq, alákoso fépo rọ̀bì, alákoso fétò ìsúná, tófimọ́ àatò gbogbo niwọ́n gbọdọ̀ gbìmọ̀ pọ̀ láti mójútó bí owó isẹ́ senlọ lẹ́ka ọ̀hún.

Ogunkọla/Net

 

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *