Ìjọba Àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ akin lórí àyíká

Killers of Kolade Johnson will be prosecuted – President Buhari
April 3, 2019
Ilé Asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ pèfún ìlanilọyẹ̀ lórí ìlòkulò òogùn
April 3, 2019
Ìjọba Àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ akin lórí àyíká

Ìjọba àpapọ̀ ti sọ pé òun kógìrì mọ́ àyíká tó wuyì fún àwọn ilésẹ́ níbamu pẹ̀lú ohun tó fún ọ̀rọ̀ àwọn òsìsẹ́ lágbayé làkalẹ̀.

Akọ̀wé àgbà nílesẹ́ ọ̀rọ̀ àwọn òsìsẹ́ àti ìgbanisísẹ́ arábìnrin William Alo ló sàlàyé yíì nílu Abuja nígbà tó gbàlejò àjọ àwọn Obìnrin lẹgbẹ́ òsìsẹ́ tó wá sàbẹ̀wò sílesẹ́ náà lórí ìpàdé àpérò ẹgbẹ́ òsìsẹ́ lágbayé nípa rògbòdìnyàn àti ìfìyàjẹni láwọn ilésẹ́ lágbayé.

Arábìnrin Mercy Okezie ló kó ikọ̀ àjọ àwọn obìnrin sòodí

Arábìnrin Alo sọ pé orílẹ̀dèèdè wa Nàijírìn ti fagilé gbogbo ìwà tó lòdì sẹ́tọ ọmọnìyàn àti yíyan ẹnikẹ́ni nípọ̀sì toripé ó ní òfin tó lòdì sí gbogbo irú ìwà bẹ́ẹ̀ tósì máà ńtẹ̀lé ìlànà tájọ àgbéyé lórí ọ̀rọ̀ àwọn òsìsẹ́ là kalẹ̀.

Ó sì pè ìfẹ́ orílẹ́èdè yíì ní láti túbọ̀ kógìirì mọ́ àti pèsè àaye tó rọrùn fún gbogbo àwọn òsìsẹ́.

Ogunkọla/Ọkareh

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *