Ilé Asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ pèfún ìlanilọyẹ̀ lórí ìlòkulò òogùn

Ìjọba Àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ akin lórí àyíká
April 3, 2019
IGP Approves Establishment of Zonal Security Stakeholders Meeting
April 4, 2019
Ilé Asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ pèfún ìlanilọyẹ̀ lórí ìlòkulò òogùn

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ ti késí àwọn ẹ̀ka alásẹ láti gùnlé ìlanilọ́yẹ̀ ìtagbangba lórí ìdí tó fiyẹ láti dẹ́kun ìlòkulò oogun lárin àwọn ọ̀dọ́.

Ìgbésẹ̀ náà wáyé lórí àbádòfin tíwọ́n fi n késí àwọn aráalu láti yàgò fúnwà lilo òogùn fún ara ẹni, àti ìlòkulò òògùn eléyi tí asòfin tún gba àwọn ilésẹ́ ètò ìlera tìjọba àti taládani nímọ̀ràn láti sọ́ra nígbà tíwọ́n bá ń kọ oogun tramadọl, Codeine fáwọn alaisan.

Bakan náà niwọ́n késí àwọn onísègùn òyìnbó láti máà sọ àwọn aláisan tíwọ́n bá ńlo Tramadọl, Codeine àtàwọn ògùn míràn.

Ẹwẹ asòfin ti fọwọ́sí àtúnse àbádòfin owo tó wà fétò ẹ̀kọ́ ọdún 2017 dòfin.

Ogunkọla/Kẹhinde

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *