Igbakeji Aare Sekilo lori Ajebanu

Onimo Daba Ileese to Nrisi Oro Molebi
May 15, 2019
Penkelemes Calls for Recount of Oyo Governorship Election Votes
May 15, 2019
Igbakeji Aare Sekilo lori Ajebanu

Igbakeji Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo ti sekilo fawon eeyan lati dehin nidi fifun awon osise ijoba lowo abetele tiwon ba fegba iwe ase iwako, iwe irina tabi iwe lati ko oja lawon ibudoko oju omi.

Ojogbon Osinbajo so eyi di mmo nilu Abuja lakoko to nsi ipade apero lori ona gbigbogunti iwa ajebanu nile Nigeria.

O salaye pe Isejoba Aare Muhammadu Buhari nsise too gbigbogunti iwa ibaje lati mu orileede yii goke agba.

Igbakeji Aare, Ojogbon Osinbajo salaye pe igbese sisamulo asuwon kan soso tare Buhari gunle sise lopo, tosi madinku ba wa ije kuje nile yi.

Ogunkola/Ayoade

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *