Onimo Daba Ileese to Nrisi Oro Molebi

Family, Friends Bid Madam Olayemi Oluseye Adieu
May 15, 2019
Igbakeji Aare Sekilo lori Ajebanu
May 15, 2019
Onimo Daba Ileese to Nrisi Oro Molebi

Onimo nipa ebi, Omowe Rapleal Okoli, ti berefun ilese ti yoo maa risi oro idile.

O soro yii dimimo, nigba to nba akoroyin wa soro, lati sami ayajo idile lagbaye, pelu alaye pe oro ebi ati igbayegbadun won gbodo je mimulokunkudun fun awujo yoowu.

Ojise olorun kan, Eniowo Edward Alabi sope pataki idile si idagbasoke awujo kose fowo roo seyin.

Eniowo Alabi bere fun ibasepo laarin ijoba atawon adari esin lati mu ile yii goke agba.

Akori ayajo ayeye ebi fun todun yii ni ‘ayipada oju ojo, igbese ati afojusun idagba soke to ye kooro’.

Ogunkola/Kupoliyi

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *