Egbe Akoroyin koro oju si titipa ileseigbohunsafefe AIT

Oyo 8th Assembly Holds Valedictory Service
June 7, 2019
Onimo Esin Gbamoran Lori Eto Aabo
June 7, 2019
Egbe Akoroyin koro oju si titipa ileseigbohunsafefe AIT

Egbe akoroyin nile wa, NUJ, ti fun ajo to nrisi igbohun safefe ni gbedeke wakati merinlelogun lati si ilese mohunmaworan AIT ati Raypower ti won tipa.

Ninu atejade ti Aare egbe naa, Ogbeni Chris Isiguzo ati Akowe, Ogbeni Shuaibu Leman fi sita ni won ti koro oju si igbese Ajo NBC.

Won salaye pe igbese yi ko fidi ominira iroyin mule, ati pe awon ona mii wa lati foju ilese iroyin toba tapa si ilana igbohunsafefe jofin.

Ajo NBC gbe ilese AIT ati Raypower lori esun pe won tapa sofin igbohunsafefe.

Ogunkola/Sherifdeen

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *